Àtòjọ Àwọn Oǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ China

Àwọn wọ̀nyí ni Àtòjọ Àwọn Oǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ China.

B

  • Consort Ban (c. 48 – c. 6 BCE) ọ̀mọ̀wé àti Akéwì
  • Ban Zhao (45 – c. 116) historian
  • Bao Junhui (fl. late 8th c. CE) Akéwì
  • Bao Linghui (fl. c. 464 CE) Akéwì
  • Anni Baobei (born 1974) oǹkọ̀wẹ́ ìtàn
  • Bing Xin (1900–1999) oǹkọ̀wẹ́ ìtàn méèrirí àti ìwé ọmọdé.

C

  • Cai Yan (c. 178 – post 206) Akéwì
  • Chang Ch'ung-ho (1914–2015) Akéwì
  • Eileen Chang (1920–1995) oǹkọ̀tàn, akàròkọ.
  • Chen Jingrong (1917–1989) Akéwì
  • Chen Danyan (born 1958) Oǹkọ̀wé nípa ìgbésí ayé ènìyàn
  • Chen Xuezhao (1906–1991) Oǹkọ̀wé àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀
  • Angelica Cheung (born 1966) Oǹkọ̀wé ẹ̀ṣọ́

D

  • Dai Houying (1938–1996) novel

Oǹkọ̀wé ìtàn àròsọ

  • Ding Ling (1904–1986) Oǹkọ̀wé ìtàn àròsọ
  • Duan Shuqing (c. 1510 – c. 1600) Akéwì

F

  • Fang Fang (born 1955) Akéwì àti oǹkọ̀tàn
  • Bu Feiyan (born 1981) oǹkọ̀tàn
  • Feng Yuanjun (1900–1974)
  • Fu Shanxiang (1833–1864) ọ̀mọ̀wé
  • Fu Tianlin (born 1946) Akéwì

G

  • Gao Yu (born 1944) oníròyìn
  • Gu Taiqing (1799 – c. 1877) Akéwì
  • Guan Daosheng (1262–1319) Akéwì

H

  • Hao Jingfang (born 1984) oǹkọ̀tàn
  • Hong Ying (born 1962) oǹkọ̀tàn àti Akéwì
  • Ganggang Hu Guidice (born 1984) Oǹkọ̀wé àti Òṣèrébìnrin
  • Hu Lanqi (1901–1994) Oǹkọ̀wé ọ̀gágun
  • Huang E (1498–1569) Akéwì
  • Madame Huarui (c. 940–976) Akéwì

J

  • Jiang Biwei (1899–1978) akọ̀wé ìrántí

K

  • Ke Yan (1929–2011) akọ̀wé eré-oníṣe, oǹkọ̀tàn àti Akéwì

L

  • Li Qingzhao (1084 – c. 1151) Oǹkọ̀wé àti Akéwì
  • Li Ye (ó kú ní 784) Akéwì
  • Liang Desheng (1771–1847) Akéwì àti Oǹkọ̀wé
  • Lin Huiyin (1904–1955) asọ̀tàn ohun-àlùmọ́nì
  • Lin Zongsu (1878–1944) akàròkọ nípa ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin
  • Ling Shuhua (1900–1990) akọ̀wé ìtàn ìgbàlódé àti oníṣẹ́ ọ̀nà
  • Liu Rushi (1618–1664) Akéwì
  • Liu Ying (born 1974) oǹkọ̀tàn
  • Lü Bicheng (1883–1943) Akéwì àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀
  • Luo Luo (born 1982) oǹkọ̀tàn
  • Lüqiu Luwei (born 1969) oníròyìn

M

  • Mian Mian (born 1970) Oǹkọ̀wé ìtàn àròsọ

P

  • Lynn Pan (born 1945) Oǹkọ̀wé ìrìn-àjò

Q

  • Qiu Jin (1875–1907) Akéwì, akàròkọ àti Oǹkọ̀wé nípa òṣèlú

R

  • Rao Xueman (wọn bí ní 1972) oǹkọ̀tàn àròsọ, aláròkọ àti oníròyìn òfegè
  • Ru Zhijuan (1925–1998) aláròkọ

S

  • Shangguan Wan'er (c. 664–710) Akéwì àti Oǹkọ̀wé
  • Shen Qing (living) Oǹkọ̀wé nípa ẹ̀ṣọ́
  • Shen Rong (born 1936) oǹkọ̀tàn àròsọ
  • Shen Shanbao (1808–1862) Akéwì àti oǹkọ̀tàn
  • Shu Ting (born 1952) Akéwì
  • Su Hui Akéwì
  • Su Qing (1914–1982) akọ̀tàn
  • Su Xiaoxiao (c. 479 – c. 501) Akéwì
  • Su Xuelin (1897–1999) Oǹkọ̀wé àti ọ̀mọ̀wé

T

  • Tian Yuan (born 1985) akọrin, akọ̀wé àti Oǹkọ̀wé
  • Tie Ning (born 1957) oǹkọ̀tàn àti oǹkọ̀tàn wẹ́wẹ́

W

  • Wang Qinghui (1264–1288) Akéwì
  • Wang Anyi (wọ́n bi lọ́dún 1954) fiction writer
  • Wang Wei (1597–1647) Akéwì
  • Wang Xufeng (wón bí lọ́dún 1955) Oǹkọ̀wé nípa ohun mímu, tíì àti oǹkọ̀tàn
  • Wang Yun (1749–1819) Akéwì àti akọ̀wé eré-oníṣe
  • Yun Wang (wọ́n bi ní ọdún 1964) Akéwì
  • Woeser (wọ́n bí ní lọ́dún 1966) blogger, poet and essayist
  • Wu Chuntao (wọ́n bi lọ́dún 1963) Oǹkọ̀wé nípa àwùjọ
  • Wu Zao (1799–1862) Akéwì

X

  • Xi Xi (wọ́n bi lọ́dún 1938) Oǹkọ̀wé àti Akéwì
  • Xia Jia (wọ́n bi lọ́dún 1984) Oǹkọ̀wé àròsọ nípa sáyẹ́ǹsì àti ìtàn méèrií
  • Xiao Hong (1911–1942) oǹkọ̀tàn ati aláròkọ
  • Xie Bingying (1906–2000) oǹkọ̀tàn nípa àwọn ènìyàn
  • Xie Daoyun Akéwì àti ọ̀mọ̀wé
  • Empress Xu (Ming dynasty) (1362–1407)
  • Lady Xu Mu (fl. 7th c. BCE) poet
  • Xu Hui (627–650) Akéwì
  • Xu Kun (born 1965) postmodern fiction writer
  • Xu Zihua (1873–1935) Akéwì
  • Xue Susu (c. 1564 – c. 1650) Akéwì
  • Xue Tao (768–831) Akéwì
  • Xinran (born 1958) akọ̀tàn

Y

  • Yang Erche Namu (wọ́n bí lọ́dún 1966) Oǹkọ̀wé nípa àwùjọ
  • Yang Gang (1905–1957) oníròyìn, oǹkọ̀tàn àti aṣògbufọ̀
  • Yang Hongying (wọ́n bi lọ́dún 1962) children's fiction writer
  • Yang Jiang (1911–2016) akọ̀wé eré-oníṣe, oǹkọ̀tàn àti aṣògbufọ̀
  • Ting-Xing Ye (wọ́n bi lọ́dún 1952) author of young adult novels
  • Ye Yingchun (born 1970) commentator
  • Chia-ying Yeh (born 1924) Akéwì ati ọ̀mọ̀wé
  • Yu Xuanji (c. 840 – c. 868) Akéwì.

Z

  • Zhai Yongming (wọ́n bi lọ́dún 1955) Akéwì
  • Lijia Zhang (wọ́n bi lodun 1964) sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀
  • Zeng Baosun (1893–1978) oǹkọ̀tàn
  • Zhang Haidi (wọ́n bi lọ́dún 1955) Akéwì àti aṣògbufọ̀
  • Zhang Jie (wọ́n bi lọ́dún 1937) oǹkọ̀tàn
  • Zhang Kangkang (wọ́n bi lọ́dún 1950) oǹkọ̀tàn
  • Zhang Ling (wọ́n bi lọ́dún 1957) oǹkọ̀tàn
  • Zhang Xinxin (wọ́n bi lọ́dún 1953) oǹkọ̀tàn nípa ìgbésí ayé ènìyàn àti oǹkọ̀tàn
  • Zhang Yaotiao (fl. 9th c. CE) Akéwì
  • Zhang Yueran (wọ́n bi lọ́dún 1982) oǹkọ̀tàn
  • Empress Zhangsun (601–636) akàròkọ
  • Zhao Luanluan (fl. mid-14th c. CE) Akéwì
  • Zhao Luorui (1912–1998) Akéwì aṣògbufọ̀
  • Zheng Min (wọ́n bi lọ́dún 1920) ọ̀mọ̀wé àti Akéwì
  • Zheng Yunduan (c. 1327–1356) poet
  • Yilin Zhong (living) fiction writer and poet
  • Zhou Weihui (wọ́n bi lọ́dún 1973) oǹkọ̀tàn
  • Zong Pu (wọ́n bi lọ́dún 1928) Oǹkọ̀wé àti ọ̀mọ̀wé
  • Zhu Lin (born 1949) oǹkọ̀tàn
  • Zhu Shuzhen (c. 1135–1180) Akéwì
  • Zhuo Wenjun (fl. 2nd c. BCE) poet
  • Zuo Fen (c. 255–300) Akéwì

Àwọn Ìtọ́kasí