2023
◄ |
Ọ̀rúndún 20k |
Ọ̀rúndún 21k
◄◄ |
◄ |
2019 |
2020 |
2021 |
2022 |
2023
Odun 2023 jẹ́ ọdún tí a wà lọ́wọ́ nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì. Ọdún 2023 bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ Àìkú nínú kàlẹ́ndà Gìrẹ́górì.
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀
Oṣù kínní
- Ọjọ́ kínní oṣù kínní(Jan 1):
- Ọjọ́ Kàrún oṣù kinni(Jan 5)– Orílè-èdè Vatican ṣe ìsìnkú Pópù Benedict XVI.[3]
- Ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní(Jan 8)
- Àjàkáyé-àrùn Covid 19: Orílè-èdè China ṣí ààlà ilẹ̀ wọn fún àwọn àlejò láti orílè-èdè míràn, èyí jẹ́ òpin sí fífi òfin de àwọn ìrìn àjò kọ̀kan èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹta ọdún 2020.[4][5]
- Ìdìbọ̀ sí ilé ìgbìmò asofin ti orílè-èdè Benin wáyé.[6]
- Ọjọ́ kẹtàlá sí ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kínní(Jan 13 – Jan 14) – Ipele àkọ́kọ́ ti Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Czech wáyé.[7]
- Ọjọ́ keedogun oṣù kínní(Jan 15)– Ọkọ̀ bàlúù kan tí wón ń pè ní Yeti Airlines Flight 691 já ní Pokhara, orílè-èdè Nepal, ó sì pa ó kéré jù, ènìyàn kandinladorin.[8]
- Ọjọ́ kerindínlógún oṣù kínní(Jan 16) – Ọwọ́ ìjọba orílè-èdè Italy tẹ olórí ẹgbẹ jàndùkú kan tí wón ti ún wá fún ọjọ́ pípé, Matteo Messina Denaro ní Palermo, Sicily.[9]
- Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kínní (Jan 17) – Nguyễn Xuân Phúc kọ̀wé fisẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ààrẹ orílè-èdè Vietnam lẹyìn ọ̀pọ̀lopọ̀ ìwóde ìfẹ̀hónúhàn tako àwọn àìsedédé ìjọba rẹ̀.[10]
- Ọjọ́ ogún oṣù kínní(Jan 20)– Àwọn asọ̀fin orílè-èdè Trínídád àti Tòbágò yan Christine Kangaloo gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè náà.[11]
- Ọjọ́ keedogbon oṣù kínní(Jan 25)– Chris Hipkins rọ́pò Jacinda Ardern gẹ́gẹ́ bi Mínísítà àgbà orílè-èdè New Zealand,[12] ọjọ́ mefa lẹ́yìn tí Jacinda Ardern kọ̀wé fi ipò mínísítà àgbà sílè.[13]
- Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n sí ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kínní (Jan 27–28) – Ipele kejì Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Czech ọdun 2023 wáyé, Petr Pavel ni ó jáwé olúborí.[14]
Oṣù Kejì
- Ọjọ́ Kàrún oṣù kejì(Feb 5) – Ìdìbọ̀ ààrẹ orílè-èdè Cypriot ti ọdún 2023 wáyé, Nikos Christodoulides sì ni ó jáwé olúborí.[15][16]
- Ọjọ́ Kẹ̀wá oṣù kejì(Feb 6) – Ìmí-ilẹ̀ Turkey àti Syria bẹ̀rẹ̀, ìmí-ilẹ̀ náà ti pa ó kéré jù ènìyàn ọ̀kànlélógójì ẹgbẹrun ní Orílẹ̀-èdè méjèèjì tí ó lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́fà ènìyàn ti fara pa.
- Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì(Feb 13)– Ìdìbọ̀ sípò ààrẹ Bangladesh tí ó yẹ kí o wáyé ní ọjọ́ kandinlogun oṣù náà wáyé, Shahabuddin Chuppu ti ẹgbẹ́ òṣèlú Awami League nìkan ni olùdíje sípò náà, ó jáwé olúborí nínú Ìdìbọ̀ náà láì ní alátakò.[17][18][19][20][21][22][23]
- Ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì(Feb 25) – Ìdìbò Gbogbogbòò Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà àti sílé ìgbìmọ̀ aṣòfin wáyé, Bola Ahmed Tinubu ni ó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ.[24][25]
Oṣù kẹta
- Ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta(March 18)– Ìdìbọ̀ sípò àwọn Gomina Nàìjíríà àti Ilé ìgbìmò aṣòfin àwọn Ìpínlẹ̀ ti ọdun 2023 wáyé.[26]
Ótún le ka
Àwọn Ìtókasí
Preview of references
- ↑ "Croatia set to join the euro area on 1 January 2023: Council adopts final required legal acts". European Council/Council of the European Union. July 12, 2022. Retrieved July 16, 2022.
- ↑ Watson, Katy (January 1, 2023). "Lula sworn in as Brazil president as Bolsonaro flies to US". BBC News. Retrieved January 1, 2023.
- ↑ "Pope Francis to lead funeral for Benedict XVI, a first in modern history". France 24 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ "China reopens borders as lunar new year travel kicks off amid Covid surge". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 January 2023. Retrieved 8 January 2023.
- ↑ "Zero-Covid over, Chinese travellers swing into overseas holiday mode". South China Morning Post (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 January 2023. Retrieved 8 January 2023.
- ↑ Linkpon, Stanislas (2022-11-09). "Législatives 2023 : plus de 6,6 millions électeurs inscrits sur la liste électorale". ORTB (in Èdè Faransé). Retrieved 2022-12-08.
- ↑ televize, Česká. "Prezidentské volby 2023". ČT24 - Česká televize (in Èdè Seeki). Retrieved 2023-01-13.
- ↑ [1]
- ↑ Italy's most-wanted mafia boss Matteo Messina Denaro arrested in Sicily. BBC
- ↑ "Vietnam legislature approves president's resignation amid graft crackdown". Reuters. January 18, 2023. https://www.reuters.com/world/asia-pacific/vietnam-legislature-approves-presidents-resignation-amid-graft-crackdown-2023-01-18/.
- ↑ Alexander, Gail. "Kangaloo is President-elect". www.guardian.co.tt (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-21.
- ↑ McClure, Tess (22 January 2023). "New Zealand: Chris Hipkins taking over from Jacinda Ardern on Wednesday". The Guardian. https://www.theguardian.com/world/2023/jan/22/new-zealand-labour-caucus-votes-in-chris-hipkins-to-succeed-jacinda-ardern.
- ↑ "Jacinda Ardern resigns: Reactions from around the world". RNZ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-01-19. Retrieved 2023-01-25.
- ↑ televize, Česká. "Prezidentské volby 2023". ČT24 - Česká televize (in Èdè Seeki). Retrieved 2023-01-29.
- ↑ "Disy leader to seek party nomination for presidency | Cyprus Mail". https://cyprus-mail.com/ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on December 22, 2021. Retrieved 2023-01-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help); External link in|website=
(help) - ↑ Kambas, Michele (2023-02-12). "Former Cyprus foreign minister wins presidential election" (in en). Reuters. https://www.reuters.com/world/middle-east/cypriot-diplomats-face-off-cliffhanger-presidential-vote-2023-02-12/.
- ↑ "Bangladesh to elect new president on Feb 19". Archived from the original on February 2, 2023. Retrieved February 2, 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "সংবাদ বিজ্ঞপ্তি" (PDF). www.ecs.gov.bd (in Bengali). Bangladesh Election Commission. Archived from the original (PDF) on February 17, 2023. Retrieved 13 February 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Correspondent, Staff. "Mohammad Shahabuddin elected 22nd president of Bangladesh". Prothomalo (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on February 14, 2023. Retrieved 2023-02-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Shahabuddin declared president-elect of Bangladesh". 13 February 2023. Archived from the original on February 13, 2023. Retrieved 13 February 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Mohammad Shahbuddin to be elected president uncontested". 12 February 2023. Archived from the original on February 13, 2023. Retrieved 13 February 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Earthquake Kills More Than 110 People in Turkey, Syria" (in en). Bloomberg.com. 2023-02-06. https://www.bloomberg.com/news/articles/2023-02-06/magnitude-7-7-earthquake-strikes-in-turkey-gfz.
- ↑ "Powerful quake kills at least 360 people in Turkey, Syria". AP NEWS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-02-06. Archived from the original on February 6, 2023. Retrieved 2023-02-06. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "JUST IN: INEC Sets New Dates for 2023 General Elections". February 26, 2022. Archived from the original on January 13, 2023. Retrieved February 16, 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "BREAKING: INEC declares Tinubu winner of presidential election". Punch Newspapers. 2023-03-01. Retrieved 2023-03-01.
- ↑ "Breaking: INEC Shifts Governorship, Assembly Elections to March 18 – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. 2023-03-09. Retrieved 2023-03-18.