Chris Tucker

Chris Tucker
Orúkọ àbísọChristopher Tucker
Ìbí31 Oṣù Kẹjọ 1971 (1971-08-31) (ọmọ ọdún 53)
Atlanta, Georgia, U.S.
Years active1988–present
GenresComedy
Ipa lọ́dọ̀Martin Lawrence
Ipa lóríDave Chappelle
Ibiìtakùnhttp://www.christucker.com/

Christopher "Chris" Tucker (born August 31, 1971)[1] je òṣeré ati aláwàdà ara ile Amerika, to gbajumo nitori isere re bi Detective James Carter ninu filmu alapameta Rush Hour ati bi Smokey ninu filmu odun 1995 Friday.


Itokasi

  1. Gates, Jr., Henry Louis (January 2009). In Search of Our Roots: How 19 Extraordinary African Americans Reclaimed Their Past. Crown. pp. 397. ISBN0307382400.