Fartuun Adan

Fartuun Adan
فرتون آدن
Adan in 2015
Ọjọ́ìbíSomalia
Iṣẹ́Activist
TitleExecutive Director of the Elman Peace and Human Rights Centre
Olólùfẹ́Elman Ali Ahmed
Àwọn ọmọ4: Almas, Ilwad and Iman

Fartuun Abdisalaan Adan jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn ti ìlú Somalia. Òun ni adarí àgbà fún Elman Peace and Human Rights Centre.

Ìgbésí ayé rẹ̀

Adan dàgbà sí ìlú Somalia. Ó fẹ́ Elman Ali Ahmed, tó jẹ́ oníṣòwò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, tó ń rí sétò àlàáfíà.[1][2] Wọ́n sì jọ bí ọmọ mẹ́rin.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

Preview of references

  1. Nima Elbagir; Lillian Leposo (5 August 2013). "Rape and injustice: The woman breaking Somalia's wall of silence". CNN. Retrieved 8 February 2014. 
  2. 2.0 2.1 "Documento - Somalia: Amnistia Internacional condena el asesinato de un pacifista". Amnesty International. Retrieved 9 February 2014.