Hassan Muhammed Gusau

Abí arákùrin Hassan Muhammed Gusau ní Ojo kejìlá osù kejìlá odún 1960 tí ó sì wolé gégé bíi asòfin àgbà ní èka zamfara central constituency ti ìjoba Ìpínlẹ̀ Zamfara ní orílè èdè Nàìjíríà tí ó sìgba ìjoba ní ojó kankàn dín lógbòn osù kaàrún odún 2007. Ó jé òkan lára omo egbé All Nigeria Peoples Party (ANPP) tí ó tùn jé alága egbé Peoples Democratic Party (PDP) ní ìpínlè Zamfara tí ó tún jé omo egbé olùdámòràn fún egbé náà. [1]

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-03-03. Retrieved 2020-03-03.