Ibikunle Amosun

Ibikunle Amosun
Senator for Ogun Central
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2019
AsíwájúLanre Tejuoso
In office
29 May 2003 – 29 May 2007
AsíwájúFemi Okurounmu
Arọ́pòIyabo Obasanjo-Bello
Governor of Ogun State
In office
29 May 2011 – 29 May 2019
AsíwájúGbenga Daniel
Arọ́pòDapo Abiodun
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kínní 1958 (1958-01-25) (ọmọ ọdún 67)
Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress (APC)
(Àwọn) olólùfẹ́Olufunso Amosun
Àwọn ọmọ3[1]

Ọjọ́ karùndílọ́gbọ̀n oṣù Ṣẹrẹ ọdún 1958 ní wọ́n bí ọ̀kan lára àwọn olóṣèlú orílẹ̀-èdè Nàíjíríà tí ó ti fi ìgbà kan jẹ gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun rí, Ìbíkúnlé Amósùn[2], bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ sẹ́nátọ̀ orílẹ̀-èdè Nigeria rí léèmejì. Oṣù Igbe 2003 sí oṣù Igbe 2007 ní Ìbíkúnlé fi jẹ sẹ́nẹ́tọ̀ fún agbèagbè àrin gbùgbù ìpínlẹ̀ Ogun, orílẹ̀-èdè Nàíjíríà. Ó di gómìnà ní ìpínlẹ̀ Ògùn lábẹ́ àsíá ẹgbé ACN ní ọdún 2011 léyìn tí ó fìdí rẹmi ní ìgbà àkọ́kọ́ tó díje dupò.[3][4] Ó díje dupò fún ipò gómìnà fún sáà kejì ní abẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú APC, lẹ́yìn tí ó wọlé, wọ́n ṣe ìbúra fún un ní ọjọ́ kankàndílọ́gbọ̀ ọṣù Èbìbí ọdún 2015.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

Preview of references

  1. "Monthly Environmental Sanitation Still Stands In Ogun State – Amosun". Channels Television. April 25, 2015. http://www.channelstv.com/2015/04/25/monthly-environmental-sanitation-still-stands-in-ogun-state-amosun/. 
  2. "Biography of Ibikunle Amosun; Accountant; Ex-Governor; Politician; Senator; Ogun State Cebebrity". biography.hi7.co. Retrieved 2022-03-30. 
  3. "Ibikunle Amosun: An enigma @ 60". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-24. Retrieved 2022-03-10. 
  4. Cite warning: <ref> tag with name Indepth20110427 cannot be previewed because it is defined outside the current section or not defined at all.
  5. "How we received ammunition from Amosun, by Ogun police command". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-06-28. Retrieved 2022-02-21.