Ibimọ
Àdàkọ:Infobox medical condition (new)
Ọmọ bíbí tí a tún lè pè ní rírọbí,ìgbésè ìbímọ àti ìbímọ máa ń ṣelẹ̀ nígbà tí oyún bá ti parí tí omọ kan tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ máa ń wáyé nípa ìbímọ ojú ara tàbí ìbímo pẹ̀lú abẹ, . [1] Ni ọdun 2019, a rí 140.11 mílíọ̀nù ìbí ènìyàn ní àgbáyé. [2] Ní àwọn orílẹ̀-èdè́ tó ti ní ìdàgbàsókè, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n ń bí omọ máa ń wáyé ní ilé-ìwòsàn, [3] [4] [ ] nígbà tí ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń dàgbàsókè púpọ̀ nínú wọn a máa bímọ sílé̀.. [5]
Ọ̀nà ìbímọ tí ó wọ́pọ̀ jùlọ ní àgbáye ni ìbímọ pẹ̀lú ojú ara,èyí sì wà ní ipele mẹ́rin ,àkókọ́ ni ìsúkì àti ṣíṣí ojú ara,jíjáde ọmọ ni ipele kejì,yíyọ ibi ọmọ ni ipele kẹta, ìmúládará ìyá àti ọmọ ni ipele kẹrin.Ipele àkọ́kọ́ yìí a máa wá pẹ̀lú inú rírun tàbí ẹ̀yìn ríro tí ó máa ń wáyé láàárín àbọ̀ ìṣẹ́jú ní gbogbo ìṣéjú mẹ́wàá sí ọgbọ̀n,ní àkókò yí rírọbí a máa le si díẹ̀díẹ̀ ìsúkì á sì máa pọ̀ si.Gẹ́gẹ́bí a ti mọ̀ wí pé ìrora ọmọ bíbí a máa jọ ìsúkì ,bẹ́ẹ̀ ìrora yí a máa wá yé léraléra bí ìrọbí ti ń ṣẹlẹ̀ . [6] . [7] . Ipele kejì yóò parí nígbàtí ọmọ bá ti jáde nínú ìyá rẹ̀. Ipele kẹta ni gbígbé ibi ọmọ jáde. [8] Ipele kẹrin ní ṣe pẹ̀lú ìmúláradá ìyá, gígé ìwọ́ àti àbójútó ọmọ tuntun. [9] Títí di 2014[update] </link></link> gbogbo àwọn ilé-iṣẹ́ elétò ìlera pátápátá ni wọ́n gbà wá ní ìmọ̀ràn pàtàkì wí pé lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́hìn ìbímọ, láìbìkítà ọ̀nà ìbímọ ó jẹ́ dandan kí a gbé ọmọ tuntun tí a bí sí àyà ìyá rẹ(tí à ń pè ní ì-fi-ara-kan-ara),kí a sún ìtọ́jú ọmọ síwájú fún bíi wákàtí kan sí méjì títí ọmọ yóò fi mu ọmú àkọ́kọ́. [10] [11] [12]
Àwọn ìtọ́kasí
Preview of references
- ↑ Concise Colour Medical l.p.Dictionary. https://books.google.com/books?id=2_EkBwAAQBAJ&pg=PA375.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Doing better for children. Paris. https://books.google.com/books?id=0Q_WAgAAQBAJ&pg=PA105.
- ↑ Planned hospital birth versus planned home birth.
- ↑ Communication for Behavior Change: Volume lll: Using Entertainment–Education for Distance Education. https://books.google.com/books?id=PWElDAAAQBAJ&pg=PT138. Retrieved 31 July 2016.
- ↑ Vaginal childbirth and pelvic floor disorders. May 2013.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Effect of timing of umbilical cord clamping of term infants on maternal and neonatal outcomes. July 2013.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)