Jim Nwobodo
Jim Nwobodo | |
---|---|
Gomina Ipinle Anambra | |
In office October 1979 – October 1983 | |
Asíwájú | D.S. Abubakar |
Arọ́pò | Christian Onoh |
Alagba Asofin fun Ilaorun Enugu | |
In office 29 May 1999 – 29 May 2003 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | May 9, 1940 Agyaragu, Lafia, Ipinle Nassarawa, Nigeria |
James Ifeanyichukwu Nwobodo tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí (Jim Nwobodo) (ni a bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù karùn-ún ọdún 1940) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà ìgbà kan ní Ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |