Joyce Banda

Joyce Banda
Ààrẹ Joyce Banda níbi àpérò
Ààrẹ ilẹ̀ Màláwì
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
7 April 2012
Vice PresidentKhumbo Kachali
AsíwájúBingu wa Mutharika
Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Màláwì
In office
29 May 2009 – 7 April 2012
ÀàrẹBingu wa Mutharika
AsíwájúCassim Chilumpha
Arọ́pòKhumbo Kachali
Alakoso Oro Okere
In office
1 June 2006 – 29 May 2009
ÀàrẹBingu wa Mutharika
AsíwájúGeorge Chaponda
Arọ́pòEtta Banda
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kẹrin 1950 (1950-04-12) (ọmọ ọdún 74)
Malemia, Nyasaland
(now Malawi)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Democratic Front (Before 2004)
Democratic Progressive Party (2004–2010)
People's Party (2011–present)
{blank1}Roy Kachale (de 1981)
Richard Banda[1]

Joyce Hilda Banda née Mtila (ojoibi 12 April 1950) je oloselu are Malawi to ti unse Aare ile Malawi lati ojo 7 Osu Kerin 2012. Banda je oluko ati alakitiyan eto awon obinrin. O wa nipo bi Alakoso Aro Okere lati 2006 de 2009 ati Igbakeji Aare ile Malawi lati May 2009 de April 2012.[2] Banda took office as President following the sudden death of President Bingu wa Mutharika. Ohun ni aare ikerin ile Malawi[3] ati aare akoko to je obinrin.



Itokasi

  1. Cite warning: <ref> tag with name malawi cannot be previewed because it is defined outside the current section or not defined at all.
  2. "Joyce Banda sworn in as new Malawi presiden". The BBC. 7 April 2012. Retrieved 7 April 2012. 
  3. Mwagiru, Ciugu (18 April 2012). "Malawi's Joyce Banda and the rise of women in African politics". Daily Monitor online (Kampala, Uganda). http://www.monitor.co.ug/artsculture/Reviews/-/691232/1388740/-/diw45/-/. Retrieved 19 April 2012.