Microlophus bivittatus
Alángba àpáta San Cristóbal (Microlophus bivittatus) jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos.[2] Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kà wọn sí ìdílé Tropidurus tẹ́lẹ̀.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ The Charles Darwin Foundation: Microlophus bivittatus
- ↑ Benavides,E; Baum, R.; Snell, H. M.; Snell, H. L.; and Sites, Jr., J. W. (2009) "Island Biogeography of Galápagos Lava Lizards (Tropiduridae: Microlophus): Species Diversity and Colonization of the Archipelago." Archived 2013-09-21 at the Wayback Machine. (.pdf) Evolution, 63 (6): 1606–1626.
- ↑ Microlophus bivittatus, Reptile Database
![]() |
Àyọkà alángbá yí jẹ́ kúkurú. Olè ran Wikipedia lọ́wọ́ lati fẹ̀ẹ́ síi. |