Moussa Camara

Moussa Dadis Camara
President of Guinea
In office
24 December 2008 – 3 December 2009
Alákóso ÀgbàKabiné Komara
AsíwájúLansana Conté
Arọ́pòSékouba Konaté (Acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1964
Koure, Guinea
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Council for Democracy and Development
Àwọn ọmọ4
Alma materUniversity of Conakry
ProfessionSoldier
WebsiteOfficial website

Moussa Dadis Camara (ojoibi 1964) je oga ologun tele ni Ise Ologun ile Guinea to di Aare orile-ede Guinea fun National Council for Democracy and Development (Conseil National de la Démocratie et du Développement, CNDD), eyi to fi tipatipa gba ijoba ni 23 December 2008 leyin iku Aare Lansana Conté. O ti kuro lori aga lati igba igbidanwo ipani to sele si ni 3 December 2009. Ni Oṣu Keje Ọjọ 31, Ọdun 2024, Moussa Dadis Camara jẹbi “awọn iwa-ipa si ẹda eniyan” ninu awọn ipakupa ti o waye ni ọdun 2009, ati pe o dajọ ọdun ogun ọdun sẹwọn.[2]



Itokasi

  1. "Qui est Moussa Dadis Camara, le nouveau president de la Guinee?" Archived 2012-02-16 at the Wayback Machine., Guineenews, 26 December 2008 (Faransé).
  2. [https://www.rfi.fr/fr/afrique/20240731-proc%C3%A8s-du-massacre-de-2009-en-guin%C3%A9e-moussa-dadis-camara-d%C3%A9clar%C3%A9-coupable-de-crimes-contre-l-humanit%C3%A9 "Afrique Procès du massacre de 2009 en Guinée: Moussa Dadis Camara condamné à 20 ans de prison pour crimes contre l’humanité"]. Radio France International. 2024-07-31. https://www.rfi.fr/fr/afrique/20240731-proc%C3%A8s-du-massacre-de-2009-en-guin%C3%A9e-moussa-dadis-camara-d%C3%A9clar%C3%A9-coupable-de-crimes-contre-l-humanit%C3%A9. Retrieved 2024-07-31.