Mutesa Kejì Buganda
Mutesa II of Buganda | |
---|---|
Kabaka of Buganda | |
Orí-ìtẹ́ | 1939 - 1969 |
Orí-oyè | November 19th, 1942 at Buddo |
Ọjọ́ìbí | November 19, 1924 |
Ibíbíbísí | Makindye, Uganda |
Aláìsí | November 21, 1969 | (ọmọ ọdún 45)
Ibi tó kú sí | London, United Kingdom |
Ìsìnkú | Kasubi Nabulagala |
Aṣájú | Daudi Chwa II of Buganda |
Arọ́pọ̀ | Muwenda Mutebi II of Buganda |
Consort | 1. Naabakyaala Damali Catherine Nnakawombe, the Naabagereka 2. Lady Edith Kasozi 3. Omubiitokati Beatrice Kabasweka 4. Lady Kate Ndagire 5. Naabakyaala Sarah Nalule 6. Muzaana Nalwooga 7. Lady Nesta M. Rugumayo 8. Lady Kaakako Rwanchwende 9. Lady Winifred Keihangwe 10. Lady Ngatho 11. Lady Catherine Karungu |
Bàbá | Daudi Chwa II of Buganda |
Ìyá | Namasole Irene Drusilla Namaganda |
Major General Sir Edward Frederick William David Walugembe Mutebi Luwangula Mutesa II KBE (November 19, 1924 – November 21, 1969), jẹ́ Kabaka ti ilẹ̀ Buganda láti November 22, 1939 títí dìgbà tó fi kú. Òun ni Kabaka karùndínlógójì ti Buganda àti ààrẹ àkọ́kọ́ ti Uganda. Wọ́n máa ń pè é ní ọba tàbí Freddie.[1]