Norbert Young

Norbert Young
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor
Notable workCheckmate
Olólùfẹ́Gloria Young

Norbert Young jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti kópa nínú àwọn fíìmù bí i Third Eye, Tinsel, àti Family Circle. Ní àfikún sí iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ-àmóhùnmáwòrán àti fíìmù àgbéléwò,[1] Young ti ṣàfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré orí-ìtàgé.[2]

Ìgbé-ayé ara ẹni

Young wà láti Ìpínlẹ̀ Delta, orúkọ ìyàwó rẹ̀ sì ni Gloria Young.[3]

Àtòjọ àwọn fíìmù tó kópa nínú

  • The Man Died (fíìmù 2024)
  • The Black Book (2023) bíi Mr. Craig
  • Choke (2022)
  • Lugard (2021) bíi Prof. Lambo
  • Day of Destiny (2021) bíi Bankole
  • RattleSnake: The Ahanna Story (2020) bíi Ali Mahmood
  • Gold Statue (2019) bíi Antar
  • King of Boys (2018) bíi Justice Nwachukwu
  • Madam President (2017) bíi Faju Omola
  • Checkmate
  • Alan Poza (2013) bíi Managing Director
  • Heroes & Zeroes (2012) bíi Nnamdi
  • Living Funeral (film) (2013) bíi Mr. Dakup
  • ZR-7:The Red House Seven (2011)
  • Quicksand[4]
  • 30 Days (2006) bíi pastor Hart[5]
  • Edge of Paradise (2006) bíi Emeka[6]
  • Missing Angel (2004) bíi Pastor James [7]

Àwọn ìtọ́kasí

Preview of references

  1. Norbert Young:- Top 5 films of talented veteran actor Archived 2017-07-21 at the Wayback Machine., Chidumga Izuzu, PulseNG. 7 March 2015, Retrieved 7 June 2015
  2. Norbert Young... It's Showtime At 50. Modern Ghana.com, 6 June 2009.
  3. Nollywood most celebrated marriages! Vanguard Nigeria. 23 February 2013
  4. "Sam Dede, Norbert Young Team-Up in Crime Thriller, QuickSand – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 1 August 2022. 
  5. "Nobert Young | Actor, Additional Crew". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-17. 
  6. "Nobert Young | Actor, Additional Crew". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-17. 
  7. "Nobert Young | Actor, Additional Crew". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-17.