Ẹ́gíptì Ayéijọ́un
Ìtàn ilẹ̀ Ẹ́gíptì | |
---|---|
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà ẹlẹ́sẹẹsẹ | |
Ẹ́gíptì Ayéijọ́un | |
Ẹ́gíptì Aṣíwájú Ìran-ọba | |
Ẹ́gíptì Ìran-ọba Àkọ́kọ́ | |
Ìgbà Ìran-ọba Ìbẹ̀rẹ̀ | |
Ilẹ̀ọba Àtijọ́ | |
Ìgbà Àpínyà Àkọ́kọ́ | |
Ilẹ̀ọba Àrin | |
Ìgbà Àpínyà Kejì | |
Ilẹ̀ọba Tuntun | |
Ìgbà Àpínyà Kẹta | |
Ìgbà Àkọ́kọ́ Akẹmẹ́nídì | |
Ìgbà Ìgbẹ̀yìn | |
Ìgbà Kejì Akẹmẹ́nídì | |
Ìgbà Ptolemy | |
Alẹksándà Ẹnínlá | |
Ptolemaic Egypt | |
Roman & Byzantine Egypt | |
Christian Egypt | |
Byzantine Egypt | |
Sassanid Occupation | |
Muslim Egypt | |
Fatimid Egypt | |
Ayyubid Egypt | |
Mamluk Egypt | |
Ottoman Egypt | |
Modern Egypt | |
French Campaign | |
Muhammad Ali Dynasty | |
Khedivate of Egypt | |
Sultanate of Egypt | |
Kingdom of Egypt | |
Republic | |
Fall of Mubarak Government | |
{Àdàkọ:Data99 | |
Èbúté Ẹ́gíptì |
Àwọn Ìran-ọba Ẹ́gíptì Ayéijọ́un |
Ẹ́gíptì Aṣíwájú Ìran-ọba |
Ìgbà Ìran-ọba Àkọ́kọ́ |
Ìgbà Ìran-ọba Ìbẹ̀rẹ̀ |
Ilẹ̀ọba Àtijọ́ |
Ìgbà Apínníyà Àkọ́kọ́ |
Middle Kingdom |
Ìgbà Apínníyà Kejì |
Ilẹ̀ọba Tuntun |
Ìgbà Apínníyà Kẹta |
First Persian Period |
Late Period |
Second Persian Period |
Ptolemaic Dynasty |
Ẹ́gíptì Ayéijọ́un ni asailaju ayeijoun ti apailaorun Ariwa Afrika, to wo jo si isale Odo Nile nibi ti orile-ede ayeodeoni Egypt wa. Asailaju ti ara Egypti gbajo ni bi odun 3150 SK (gegebi Iseoroasiko apejose ti ara Egypti )[1] pelu isodokan oselu Apa Oke ati Apa Isale Egypti labe farao akoko.[2] Itan Egypti ayeijoun sele bi eseese awon Ileoba, ti won je pinpinniya pelu awon igba aitoro ti won unje Igba Apinniya. Ileoba Atijo ti Igba Ibere Amobaba, Ileoba Arin ti Igba Arin Amobaba ati Ileoba Tuntun ti Igba Opin Amobaba. Egypti de ogo agbara re nigba Ileoba Tuntun, ni igba Ramesi, leyin eyi ni obere si ni bo si igba irele diedie. Egypt je sisegun latowo awon alagbara okere ni titelentele. Leyin iku Aleksanda Eninla, ikan ninu awon ogagun re to unje Ptolemy Soter, so ara re di ajoba tuntun Egypt. Iran-oba Ptolemi yi joba lori Egypt titi de odun 30 SK, nigba to bo sowo Ile Romu to si di igberiko Romu.[3]
Ijasirere asailaju Egipti ayeijoun je be nitori agbara re lati le gbe pelu awon isele Ifonofoji Odo Nilo. Agbara asotele ati ikojanu ibomirin ile olora inu afonifoji fa opo eso ogbin wa, eyi lo si mu idagbasoke awujo ati asa wa. Pelu opo ohun amulo o se ese fun ijoba lati segbowo imulo awon alumoni to wa ni afonifoji Nilo ati awon agbegbe ashale to yika, atetebere idagbasoke sistemu ikoole fun ra ara won, igbajo ikole akojopo ati awon iseowo iseagbe, idunadura pelu awon agbegbe ayika, ati ise ologun to fe segun awon ota okere to si le fi agbara Egypti han. Lati sakoso awon agbese wonyi ni awon akowe, olori esin, ati awo aseamojuto labe ijanu Farao, eni to ridaju pe awon eniyan ara Egipti wa lokan labe sistemu awon igbagbo esin.[4][5]
Ninu awon opo oriire awon ara Egipti ayeijoun ni okuta fifo, ile wiwon ati awon ona ikole to fa kiko awon piramidi gbangba, tempili, ati obeliski; sistemu mathimatiki, sistemu iwosan to sise ati to se e mulo, awon sistemu ibomirin ati ona ida iseagbe, awon oko-ojuomi akoko, amo fiyansi Egypti ati iseoroiseona digi (gilasi), iru isemookomooka tuntun, ati adehun alafia atetejulo ti a mo.[6] Egypt left a lasting legacy. Its art and architecture were widely copied, and its antiquities carried off to far corners of the world. Its monumental ruins have inspired the imaginations of travellers and writers for centuries. A new-found respect for antiquities and excavations in the early modern period led to the scientific investigation of Egyptian civilization and a greater appreciation of its cultural legacy.[7]
Ìtàn
Ìgbà aṣíwájú ìran-ọba
ṣaaju ki Oba (ọdun 3150–2686)
Ijọba atijọ (2686–2181)
Akoko (2181–2055)
Laarin (2134–1690)
Keji (1674–1549)
Ijọba Tuntun (1549–1069)
Kẹta (1069–653)
Nigbamii (653–332)
Πτολεμαῖος Σωτήρ (332–30)
Ilẹ̀ọbalúayé Rómù Apáìwọ̀orùn (30 – 641)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |