Ata Tàtàṣé
Ata Tàtàṣé (Látìnì: capsicum annuum) ni wọ́n tún ń dà pe ní sweet pepper, bell pepper, paprika tàbí ní èdè Gẹ̀ẹ́sì /ˈkæpsᵻkəm/)[1][2] Ata yí ma ń ní ẹ̀yà ewébẹ̀ tí a fi ń ṣe ohun jíjẹ, tí ó ma ń ní oríṣiríṣi àwọ̀ bí :àwọ̀ pupa, funfun, àwọ̀ ewé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ata tàtàṣé kìí sábà ta ní tirẹ̀, nítorí wípé ó ma ń dùn ní tirẹ̀ .[3] agbègbè tí ata yí ti fẹ́ràn jùlọ láti màa dàgbà aí ni ibi tí ó bá lọ́ wọ́rọ́ bí ìwòn 21 to 29 °C (70 to 84 °F).[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ Wells, John C. (2008), Longman Pronunciation Dictionary (3rd ed.), Longman, p. 123, ISBN 9781405881180
- ↑ "Capsicum annuum (bell pepper)". CABI. 28 November 2017. Retrieved 15 March 2018.
- ↑ Sasvari, Joanne (2005). Paprika: A Spicy Memoir from Hungary. Toronto, ON: CanWest Books. p. 202. ISBN 9781897229057. https://books.google.com/books?id=cdfiz5IS22QC&dq. Retrieved 20 October 2016.
- ↑ "Growing Peppers: The Important Facts". GardenersGardening.com. Archived from the original on 27 January 2013. Retrieved 10 January 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)