Josip Broz Tito
Marshal Josip Broz Tito | |
---|---|
Fáìlì:Marsal Tito.jpg | |
1st Secretary-Generalof the Non-Aligned Movement | |
In office 1 September 1961 – 10 October 1964 | |
Asíwájú | Position created |
Arọ́pò | Gamal Abdel Nasser |
2nd President of SFR Yugoslavia | |
In office 14 January 1953 – 4 May 1980 | |
Alákóso Àgbà | Himself (1953–1963) Petar Stambolić (1963–1967) Mika Špiljak (1967–1969) Mitja Ribičič (1969–1971) Džemal Bijedić (1971–1977) Veselin Đuranović (1977–1982) |
Asíwájú | Ivan Ribar (as President of the Presidency of the People's Assembly) |
Arọ́pò | Lazar Koliševski (as President of the Presidency of SFR Yugoslavia) |
1st Prime Minister of SFR Yugoslavia President of the Federal Executive Council | |
In office 29 November 1943 – 29 June 1963 | |
Ààrẹ | Ivan Ribar (1945–1953) Himself (1953–1963) |
Asíwájú | Position created |
Arọ́pò | Petar Stambolić |
1st Federal Secretary of People's Defence | |
In office 29 November 1945 – 14 January 1953 | |
Alákóso Àgbà | Himself |
Asíwájú | Position created |
Arọ́pò | Ivan Gošnjak |
7th Chairman of the League of Communists of Yugoslavia | |
In office November 1936 – 4 May 1980 | |
Asíwájú | Milan Gorkić |
Arọ́pò | Branko Mikulić |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 7 or 25 May 1892 Kumrovec, Croatia-Slavonia, Austria-Hungary |
Aláìsí | 4 May 1980 Ljubljana, SR Slovenia, SFR Yugoslavia | (ọmọ ọdún 87)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Yugoslav |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | League of Communists of Yugoslavia (SKJ) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Pelagija Broz (1919-1939), div. Herta Haas (1940-1943) Jovanka Broz (1952-1980) |
Domestic partner | Davorijanka Paunović |
Àwọn ọmọ | Zlatica Broz, Hinko Broz, Žarko Leon Broz and Aleksandar Broz |
Occupation | Machinist, revolutionary, resistance commander, statesman |
Awards | 119 awards, among others: Order of the People's Hero Légion d'honneur Order of the Bath OMRI (short list below, full list in the separate article) |
Signature | |
Military service | |
Allegiance | Austria-Hungary SFR Yugoslavia |
Branch/service | Yugoslav People's Army All (supreme commander) |
Years of service | 1913-1915 1941–1980 |
Rank | Marshal of Yugoslavia |
Commands | Yugoslav Partisans Yugoslav People's Army |
Battles/wars | World War I Spanish Civil War World War II |
Josip Broz Tito (bibi bi Josip Broz; 7 or 25 May 1892 – 4 May 1980) je ara ile Yugoslafia to je olujidide ati agbailu.[1] Ohun lo je Akowe Agba (o di Aare leyin) Egbe awon Komunisti ile Yugoslafia (1939–80), o si lewaju irinkankan agbogun Yugoslafia nigba Ogun Agbaye Keji, ati awon Partisan Yugoslafia (1941–45).[2] After the war, he was the authoritarian[3][4][5] Alakoso Agba (1943–63) ati leyin re Aare (1953–80) Orile-ede Olominira Sosialisti Apapo (SFRY). Lati 1943 di ojo iku re ni 1980, o di ipo Kakanfo ile Yugoslafia mu, nibi to ti je alase patapata ile ise ologun Yugoslafia, eyun Yugoslav People's Army (JNA).
Tito lo je bi eni to sedasile "Yugoslafia keji", ile apapo sosialisti to wa lati Ogun Agbaye Keji de 1991. Botilejepe o je ikan ninu awon oludasile egbe Cominform, ohun na tun ni eni akoko (ti yio yori si rere) omo egbe Cominform to lodi si ilelori Sofieti.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
- ↑ "Josip Broz Tito". Encyclopædia Britannica Online. Retrieved 27 April 2010.
- ↑ Bremmer, Ian (2007). The J Curve: A New Way to Understand Why Nations Rise and Fall. Simon & Schuster. p. 175. ISBN 0743274725.
- ↑ Cohen, Mark F.; Fidler, Jay W. (2002). Group Psychotherapy and Political Reality: A Two-Way Mirror. International Universities Press. p. 193. ISBN 0823622282.
- ↑ Andjelic, Neven (2003). Bosnia-Herzegovina: The End of a Legacy. Frank Cass. p. 36. ISBN 071465485X.
- ↑ Tierney, Stephen (2000). Accommodating National Identity: New Approaches in International and Domestic Law. Martinus Nijhoff Publishers. p. 17. ISBN 9041114009.