Kenya
Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà Republic of Kenya Jamhuri ya Kenya (Swahili)
| |
---|---|
Motto: "Harambee" (Swahili) "Let us all pull together" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Nairobi 1°16′S 36°48′E / 1.267°S 36.800°E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | |
National language | Swahili[1] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2019[2]) |
|
Ẹ̀sìn (2019[2]) | Àdàkọ:Ublist |
Orúkọ aráàlú | Kenyan |
Ìjọba | Unitary presidential constitutional republic |
• Ààrẹ | Uhuru Kenyatta |
• Ìgbákejì Ààrẹ | William Ruto |
• Speaker of the Senate | Kenneth Lusaka |
• Speaker of the National Assembly | Justin Muturi |
• Chief Justice | David Maraga |
• Attorney General | Paul Kihara Kariuki |
Aṣòfin | Parliament |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Senate |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | National Assembly |
Independence | |
• from the United Kingdom | 12 December 1963 |
• Republic declared | 12 December 1964 |
Ìtóbi | |
• Total | 580,367 km2 (224,081 sq mi)[3][4] (48th) |
• Omi (%) | 2.3 |
Alábùgbé | |
• 2019 census | 47,564,296[5] (29th) |
• Ìdìmọ́ra | 78/km2 (202.0/sq mi) (124th) |
GDP (PPP) | 2020 estimate |
• Total | $206.532 billion[6] |
• Per capita | $4,071[7] |
GDP (nominal) | 2020 estimate |
• Total | $109.116 billion[7] |
• Per capita | $2,151[7] |
Gini (2014) | 42.5[8] medium · 48th |
HDI (2018) | ▼ 0.579[9] medium · 147th |
Owóníná | Kenyan shilling (KSH) |
Ibi àkókò | UTC+3 (EAT) |
Irú ọjọ́ọdún | dd/mm/yy (AD) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +254 |
Internet TLD | .ke |
[10] According to the CIA, estimates for this country explicitly take into account the effects of mortality because of AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex, than would otherwise be expected. |
Kẹ́nyà tàbí Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà je orile-ede ni Ìlaòrùn Áfríkà. O dubule si eba Okun India, ni agedemeji aye, Kẹ́nyà ni bode mo Ethiópíà (ariwa), Sòmálíà (ariwailaorun), Tànsáníà (guusu), Ùgándà ati Lake Victoria (iwoorun), ati Orile ede Gúúsù Sudan (ariwaiwoorun). Oluilu re ni Nairobi. Awon onibugbe ibe ti po to 38 legbegberun.
Awon Igberiko, ibile ati awon ipinsi
Kenya pinsi awon igberiko 8 ti olori won n je Alakoso Igberiko (Aare lo n yan won). Awon igberiko wonyi (mkoa singular mikoa plural in Swahili) na tun je pinpin si awon ibile (wilaya). Awon ibile 69 lo wa. Awon ibile wonyi na tun je pipin si awon ipinsi 497 (taarafa). Awon ipinsi tu je pipin si 2,427 awon ibudo 2,427 (mtaa) ati omo ibudo 6,612 (mtaa mdogo).[11]. Awon igberiko na niwonyi:
- Igberiko Aarin
- Igberiko Eti Okun
- Igberiko Apailaorun
- Igberiko Nairobi
- Igberiko Ariwa Apailaorun
- Igberiko Nyanza
- Igberiko Rift Valley
- Igberiko Apaiwoorun
Iye awon onibugbe awon ilu ninla
Ilu | Iye eniyan |
---|---|
Nairobi | 2 940 911 |
Mombasa | 707 400 |
Nakuru | 337 200 |
Kisumu | 273 400 |
Eldoret | 249 100 |
Nyeri | 213 000 |
Machakos | 179 500 |
Meru | 140 900 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
- ↑ 1.0 1.1 Constitution (2009) Art. 7 [National, official and other languages] "(1) The national language of the Republic is Swahili. (2) The official languages of the Republic are Swahili and English. (3) The State shall–-–- (a) promote and protect the diversity of language of the people of Kenya; and (b) promote the development and use of indigenous languages, Kenyan Sign language, Braille and other communication formats and technologies accessible to persons with disabilities."
- ↑ 2.0 2.1 "2019 Kenya Population and Housing Census Volume IV: Distribution of Population by Socio-Economic Characteristics". Kenya National Bureau of Statistics. Retrieved 24 March 2020.
- ↑ "Demographic Yearbook – Table 3: Population by sex, rate of population increase, surface area and density" (PDF). United Nations Statistics Division. 2012. Retrieved 4 September 2017.
- ↑ "United Nations Statistics Division - Demographic and Social Statistics". unstats.un.org.
- ↑ "2019 Kenya Population and Housing Census Results". Kenya National Bureau of Statistics. 4 November 2019. Retrieved 15 November 2019.
- ↑ "Report for Selected Countries and Subjects (valuation of Kenya GDP)". International Monetary Fund.
- ↑ 7.0 7.1 7.2 "World Economic Outlook Database, April 2019". IMF.org. International Monetary Fund. Retrieved 15 June 2019.
- ↑ "Human Development Report 2014" (PDF). United Nations. 2014. Retrieved 26 July 2014.
- ↑ "Human Development Report 2019" (PDF) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). United Nations Development Programme. 10 December 2019. Retrieved 10 December 2019.
- ↑ Cite warning:
<ref>
tag with namecia
cannot be previewed because it is defined outside the current section or not defined at all. - ↑ Central Bureaus of Statistics (Kenya): Census cartography: The Kenyan Experience
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Kenya |