Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia
Socijalistička Federativna Republika Jugoslavijaa Социјалистичка Федеративна Република ЈугославијаbSocialistična federativna republika Jugoslavijac Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia Socialist Federal Republic of Yugoslavia
a State name in Serbo-Croatian and Macedonian languages (the name is identical in both), spelled in the Latin alphabet. (See Etymology section for details.) b State name in Serbo-Croatian and Macedonian languages (the name is identical in both), spelled in the Cyrillic alphabet. (See Etymology section for details.) c State name in the Slovene language. Slovene used the Latin alphabet exclusively. (See Etymology section for details.)
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia (Socialist Federal Republic of Yugoslavia; SFRY) je orile-ede Yugoslafia to wa lati igba Ogun Agbaye Keji (1943) titi di igba to je tituka deede ni 1992 larin awon Ogun Yugoslafia. O je orile-ede sosialisti ati ile apapo to ni awon orile-ede olominira mefa: Bosnia ati Herzegovina, Kroatia, Macedonia, Montenegro, Serbia, ati Slovenia. Serbia, bakanna, tun ni igberiko aladawa meji ti Vojvodina ati Kosovo.