Twa

Twa
Mutwa with traditional bow and arrow
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
80,000
Regions with significant populations
Rwanda, Burundi, Congo, Tanzania, Uganda
Èdè

Kinyarwanda, Kirundi, Rukiga

Ẹ̀sìn

7% Christian[1]

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Hutu, Tutsi

Twa tabi Batwa jé àwon èyà ènìyàn kúkuru (pigmy) tí a le pè ní àràrá. Àwọn ni Olùgbé tí a ní àkọsílẹ̀ pé ó pẹ́ jù ní àarin gbùngbùn ìlẹ Afíríka nibi tí a ti rí àwọn orílẹ̀-èdè bí Rwanda, burunidi ati Ilẹ̀ olomìnira ti Congo lóde òní. Àwọn ará Hutu tó sẹ̀ wá láti àwọn ara Bantu jọba lé Twa lori nígbà tí wọ́n dé agbègbè náà ṣùgbọ́n nígbà tó di bí ẹgbẹ̀rún ọdun ìkẹẹ̀dógún (15th century AD) ni Tustsi fó jẹ́ ara ẹ̀yà Bantu dé sí agbègbè náà ti wọ́n sì jẹ ọba lórí Twa àti Hutu ti wọ́n ba lórí ìlẹ náà. Àwọn ènìyàn Twa ń sọ èdè Kwyarwanda èyí ti àwọn ènìyàn Tutsi ati Hutu n sọ.


  1. Johnstone, Patrick, and Jason Mandryk. Operation World. Waynesboro, GA: Paternoster Lifestyle, 2001.